Ṣóẹ̀tán
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣóẹ̀tán
1. Sorcery has not finished; The sorcerer's lineage has not finished 2. Sorcery has finished.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-ẹ̀-tán
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, òrìṣà oko, the god of fertilityẹ̀ - not
tán - complete(ly), finish
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
OGUN