Ṣàngónúgà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣàngónúgà
Ṣàngó has a throne.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ṣàngó-ní-ùgà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ṣàngó - Ṣàngó, Yorùbá thunder godní - have
ùgà - throne, position, prominence
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU