Ṣàngódínà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣàngódínà

Ṣàngó blocked the way (of our enemies).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ṣàngó-dí-ọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ṣàngó - Ṣàngó, Yorùbá thunder god
- to block
ọ̀nà - road, lane, way, path


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Shàngódínà

Dínà