Ùjádélí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ùjádélí
A variation of Ìjádélé, Ùja (Ìja) has arrived at the home.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ùja-dé-ulí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ùja - Ìja, a hunting deity regarded as the brother of Ògún; hunting goddessdé - arrive
ulí - house, home (ilé)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO