Ùṣẹ́núgà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ùṣẹ́núgà

Ùṣẹ̀n has a throne.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ùṣẹ̀n-ní-ùgà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ùṣẹ̀n - Ùṣẹ̀n, an Ìjẹ̀bú ancestral deity
- to have, own
ùgà - throne, position, prominence


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Ṣẹ̀núgà

Ṣẹ̀nnúgà

Shẹ̀núgà

Shẹ̀nnúgà