Ùṣẹ́nbánkẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ùṣẹ́nbánkẹ́
Ùṣẹ̀n helped me care (for this child).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ùṣẹ̀n-bá-n-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ùṣẹ̀n - Ùṣẹ̀n, an Ìjẹ̀bú deitybá - together with
n - me
kẹ́ - cherish, care for, pet, pamper
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU