Òsédíminẹ́yìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Òsédíminẹ́yìn
Òsé allowed me to have a legacy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
òsé-dí-mi-ní-ẹ̀yìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
òsé - Òsé (goddess of the Ose river)dí - to allow (jí, jẹ́)
mi - me, my
ní - have, own; in
ẹ̀yìn - back, behind, future
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO