Òrìṣágúnnà

Sísọ síta



Ìtumọọ Òrìṣágúnnà

Òrìṣà aligns one's path (to be good).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

òrìṣà-gún-ọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

òrìṣà - the òrìṣà, Ọbàtálá (Sky god)
gún - be proper, be appropriate, be just
ọ̀nà - road, pathway


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OSUN
GENERAL



Irúurú

Ṣágúnnà

Shágúnnà

Ọ̀ṣágúnnà

Òrìṣágúnà

Ọ̀shágúnà

Ọ̀ṣágúnà