Òkéwọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Òkéwọlá
The deity of the mountain/hills has entered our honor.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
òkè-wọ-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
òkè - Deity of the mountain/hill; mountain, hill, Òkè Ìbàdànwọ - enter
ọlá - wealth, success
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA