Òkérúkù
Sísọ síta
Ìtumọọ Òkérúkù
The hill deity has opened the door (way).
Àwọn àlàyé mìíràn
Nickname of the Alárá of Ìlárá-Mọ̀kín, Alárá Òkérúkù (r. 1918-1937), the full apellation is Òkérúkùṣọrọ̀ - The hill opened the door to make wealth.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
òkè-rúkù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
òkè - Deity of the mountain/hill; mountain, hill, Òkè Ìbàdànrúkù - seen the way, opened the door
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE