Òkélàrín

Sísọ síta



Ìtumọọ Òkélàrín

The hill is the middle (the center of attention).



Àwọn àlàyé mìíràn

A male child among several female siblings. - User comment



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

òkè-ni-àárín



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

òkè - Deity of the mountain; mountain, hill, Òkè Ìbàdàn
ni - is
àárín - middle


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Làrín