Òkélàrín
Sísọ síta
Ìtumọọ Òkélàrín
The hill is the middle (the center of attention).
Àwọn àlàyé mìíràn
A male child among several female siblings. - User comment
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
òkè-ni-àárín
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
òkè - Deity of the mountain; mountain, hill, Òkè Ìbàdànni - is
àárín - middle
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU