Òkébùnmi
Sísọ síta
Ìtumọọ Òkébùnmi
The deity of the hill gifted (this child) to me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
òkè-bùn-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
òkè - Deity of the mountain/hill; mountain, hill, Òkè Ìbàdànbùn - to give, to gift
mi - me, my
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN