Ògúnyẹyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnyẹyè

Ògún is worthy of a chieftaincy title.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-yẹ-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron
yẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
oyè - honor, chieftaincy ttle


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI