Sísọ síta
Ògún is worthy of praise.
ògún-tú-ìyìn
Ó pọ̀ ní: EKITI
Ògúntóyìn
Tóyìn
Túyìn
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.