Ògúntúlà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúntúlà
Ògún has survived again.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-tún-là
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technologytún - again
là - to survive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI