Ògúntòkunbọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúntòkunbọ̀
Ògún has come from across the ocean.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-ti-òkun-bọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technologyti - from
òkun - sea, ocean
bọ̀ - to return
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI