Ògúnmoyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnmoyè

Ògún knows honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-mọ-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron
mọ - know
oyè - honor, chieftaincy ttle


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Moyè