Ògúnmorótì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnmorótì
Ògún is who I stand with.
Àwọn àlàyé mìíràn
Ògúnrótìmí
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-mo-ró-tì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technologymo - I
ró - stand (dúró)
tì - with
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI