Ògúnmilúà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnmilúà
My Ògún has a gathering of people; My Ògún is popular.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-mi-ní-ùà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technologymi - me
ní - have, own; into
ùà - the society, a gathering, celebration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI