Ògúnmiládé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnmiládé

My Ògún has a crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-mi-ní-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology
mi - me
- have, own; into
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI