Ògúnmókùnadéró

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnmókùnadéró

Ògún upholds the royal beads.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-mú...ró-okùn-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology; a type of sacred tree
mú...ró - uphold
okùn - rope, thread, wealth
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ògúnmókùn

Ògúnmókùnadé