Ògúnmọ́láṣuyì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnmọ́láṣuyì
Ògún used honor to create something valuable.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-mú-ọlá-ṣe-uyì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, Yorùbá god of ironmú - to use; to hold (onto)
ọlá - wealth/nobility/success
ṣe - make
uyì - honour, prestige (iyì)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI