Ògúnjẹ́misìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnjẹ́misìn
Ògún gave me a reason to worship.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-jẹ́-mi-sìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, Yorùbá god of ironjẹ́ - permit, to exist, to be effective
mi - me
sìn - worship
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI