Ògúnjẹ́milà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnjẹ́milà
1. Ògún allowed me to become rich 2. Ògún allowed me to survive.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-jẹ́-mi-là
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, Yorùbá god of ironjẹ́ - permit, to exist, to be effective
mi - me
là - survive, succeed, salvation
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI