Ògúngbùjì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúngbùjì
Ogun can withstand the storm.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-gba-ùjì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, Yorùbá god of irongba - to collect, to receive, to take
ùjì - wind (ìjì)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI