Ògúnfidódò

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnfidódò

Ògún used (this child) to block the river. [verification needed]



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-fi-dí-odò



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology
fi - use, put
- to block
odò - river


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IFE



Irúurú

Fidódò