Ògúnfìdítìmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnfìdítìmí
Ogun helped motivate/support me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-fi-ìdí-tì-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, the Yorùbá god of ironfi - use (it/him/her)
ìdí - bottom, butt
tì - push
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO