Ògúndùlú

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúndùlú

Ògún has become (as vast as) the town.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-di-ùlú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology
di - become
ùlú - town (ìlú)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Dùlú