Ògúndólírẹ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúndólírẹ̀
Ògún has established his household.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-dó-ulí-rẹ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, Yorùbá god of irondó - started, establish, founded
ulí - house, home (ilé)
rẹ̀ - his, hers
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO