Ògúndímbọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúndímbọ́lá
Ògún did not block me from meeting honor. [verification needed]
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-dí-m-bá-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, the god of iron, war, hunting, and technologydí - block
m - me
bá - together with, to meet
ọlá - honour, wealth, success, notability
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO