Ògúndèmúrẹ̀n
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúndèmúrẹ̀n
Ogun has added another (child/devotee); Ogun has multiplied.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Oshódèmúrẹ̀n, Ọnádèmúrẹ̀n
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-di-èmúrẹ̀n
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - ògún, the god of iron and technologydi - become
èmúrẹ̀n - another (òmíràn, ìmíì)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU