Ògúnbùsúyì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnbùsúyì
Ògún has added to (our) honor.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ò-gún-bù-sí-uyì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ò - is not, does notgún - set, to align, to be good.
bù - to add to, to scoop
sí - into
uyì - iyì: honour, regard, respect
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI