Ògúnbóyèwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnbóyèwá

Ògún has come with a chieftaincy title.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-bá-oyè-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron
- together with
oyè - honor, chieftaincy ttle
- to find, to come


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Bóyèwá