Ògúnbámiṣe

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnbámiṣe

Ògún helped me to do it.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-bá-mi-ṣe-é



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology
- together with
mi - me, mine
ṣe - make
é - it


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Bámiṣe