Ògúnṣetirẹ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnṣetirẹ̀

1. Ògún has done its own. 2. Ògún has done (great) for this child.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-ṣe-tirẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology
ṣe - make
tirẹ̀ - his/her own


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI