Ọ̀ṣátógbè
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣátógbè
Òrìṣà is worthy of being supported.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣà-tó-gbè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣà - Òrìṣà, the supreme sky deity Ọbàtálátó - sufficient for, big enough for
gbè - support
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI
ONDO