Ọ̀rìṣájuyìgbé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀rìṣájuyìgbé
Òrìṣà did not allow (my) honor to perish.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Fájuyìgbé
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀rìṣà-à-jẹ-uyì-gbé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀rìṣà - Orisha, the supreme Yoruba sky god (Ọbàtálá), Olódùmarèà - did not
jẹ - let
uyì - honour (iyì)
gbé - to perish
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI