Ọ̀pátáyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀pátáyọ̀
Ọ̀pá (symbol of the deity Òrìṣàoko) is worthy of joy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀pá-tó-ayọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀pá - staff; a symbol of the deity Òrìṣàokotó - suffice for
ayọ̀ - joy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN
OYO