Ọ̀jẹ́wándé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀jẹ́wándé
The Eégún worshipper sought me out.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀jẹ̀-wá-mi-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀jẹ̀ - Egúngún (masquerade) worshipper, lineage of masquerade worshipperswá - to find
mi - me, my
dé - come, return, arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OYO