Ọ̀jẹ́sanmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọ̀jẹ́sanmí

Being an Eégún masquerade worshipper has paid off.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọ̀jẹ̀-san-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọ̀jẹ̀ - Egúngún (masquerade) worshipper, lineage of masquerade worshippers
san - pay, benefit
- breathe


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Ọ̀jẹ́san