Ọ̀gbẹ̀sẹ́tádé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀gbẹ̀sẹ́tádé
The Ọ̀gbẹ̀sẹ̀ deity is worthy of a crown.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀gbẹ̀sẹ̀-tó-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀gbẹ̀sẹ̀ - An androgynous river deity of the Ekiti/Akure region, and child of Olókuntó - suffice for, to be equal to, worthy
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE