Ọ̀ṣúnsanwó
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣúnsanwó
Ọ̀ṣun paid (a high cost) for this child.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣun-san-owó
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣun - Yorùbá river goddess of fertility and beautysan - pay, benefit
owó - money, cowries
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL