Ọ̀ṣúnnáìkè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọ̀ṣúnnáìkè

Osun (or her devotees) has prominence.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọ̀ṣun-ní-àìkè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọ̀ṣun - Osun, Yoruba goddess of fertility and beauty
- have
àìkè - prominence (or òkìkí)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU