Ọ̀ṣúnlàbákẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣúnlàbákẹ́
Ọ̀ṣun is the one we should care for.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣun-ni-à-bá-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣun - Yorùbá river goddess of fertility and beautyni - is
à - we
bá - should have
kẹ́ - cherish, care for, pet
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL