Ọ̀ṣúngbèmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣúngbèmí
HOMOGRAPH Ọ̀ṣúngbèmí 1. Ọ̀ṣun supports me. Ọ̀ṣúngbémi 2. Ọ̀ṣun carries me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣun-gbé-mi, ọ̀ṣun-gbè-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣun - Ọ̀ṣun, Yoruba river goddess of fertility and beautygbé - carry
mi - me
gbè - support, benefit, befit
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL