Ọ̀ṣáránmáyé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣáránmáyé
Ọ̀rìṣà sent me to the world.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣà-rán-mi-sí-ayé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣà - Òrìṣà, the supreme sky deity Ọbàtálárán - send
mi - mine
sí - into, towards
ayé - world
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI