Ọ̀ṣákúà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọ̀ṣákúà

A shortening of Ọ̀ṣákúàdé, Ọ̀rìṣà has brought a celebration.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọ̀ṣà-kó-ùà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọ̀ṣà - Òrìṣà, the supreme sky deity Ọbàtálá
- to bring
ùà - the society, a gathering


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE
EKITI



Irúurú

Ọ̀ṣákúàdé