Ìyádùnní

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìyádùnní

Mother is sweet to have.



Àwọn àlàyé mìíràn

Also sometimes written as "Ìyádùní" or Ìyádùn-ń-ní.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìyá-dùn-ní



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìyá - mother
dùn - sweet
ni - have


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dùnní