Ìwáyẹyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìwáyẹyè

Good character befits honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìwà-yẹ-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìwà - character
yẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
oyè - honor, chieftaincy ttle


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Yẹyè